adesinaabegunde_yo_mat_text.../13/24.txt

1 line
364 B
Plaintext

\v 24 Jésù pa òwe míràn fún wọn wípé, "Ìjọba ọ̀run dàbí ọkùnrin kan tí ó gbin irúgbìn rere sínú ọgbà rẹ̀. \v 25 Ṣùgbọ́n nígbàtí ènìyàn sùn, ọ̀tá rẹ̀ wá, Ó sì gbin èpò sínú àlìkámọ̀, ó bá tirẹ̀ lọ. \v 26 Nígbàtí irúgbìn na ń yọ ewé, tí ó sì ń so èso, èpò pẹ̀lú farahàn.