adesinaabegunde_yo_mat_text.../12/24.txt

1 line
450 B
Plaintext

\v 24 Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Farisí gbọ́ àwọn iṣẹ́ ìyanu yìí, wọ́n wípé, "ọkùnrin yìí kò lé ẹ̀mí èṣù jáde, bí kò ṣe nípasẹ̀ Beelzebul, ọmọba àwọn ẹ̀mí èṣù" \v 25 Sùgbọ́n Jésù mọ èro wọn, ó sì wí fún wọn pé, "Gbogbo ìjọba tí ó bá ní ìpinyà nínú rẹ̀ ni yóò di ahoro, àti ìlú tàbí ilé tí ó bá ní ìpinyà nìnù rẹ̀ ni kì yóò dúró.