adesinaabegunde_yo_mat_text.../11/23.txt

1 line
365 B
Plaintext

\v 23 Ìwọ, Kápánámù, sé o rò wípé a óò gbé ọ ga sí ọ̀run? Rárá o, inú ọ̀gbun ilẹ̀ ni a óò jù ọ́ sí. Nítorí kání Sódómù ni a ti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu tí a ṣe nínú rẹ̀, yóò sì wà títí di òní. \v 24 Mo ṣọ fún yín wípé yóò sàn fún ilẹ̀ Sódómù jù yín lọ lọ́jọ́ ìdájọ́."