adesinaabegunde_yo_mat_text.../11/13.txt

1 line
278 B
Plaintext

\v 13 Nítorí gbogbo áwọn Wòólì àti òfin ló ti ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ títí àkókò Jòhánù, \v 14 tí ẹ̀yin bá sì lé gbàá, òun ní Èlíjà tí a ti sọ wípé yíò wá. \v 15 Ẹni tó bá létí láti gbọ́ràn, ẹ jẹ́ kí ó tẹ́tí.