adesinaabegunde_yo_mat_text.../11/11.txt

1 line
405 B
Plaintext

\v 11 Lóòtọ́ ni mo wí fún yín, láàrin àwọn tí a bí nínú obìnrin, kò sí ẹnití ó gajù Jòhánù onítẹ̀bọmi lọ. Síbẹ̀ ènìyàn pàtàkì tó kéré jù ní ìjọba ọ̀run jùú lọ. \v 12 Láti ìgbà tí Jòhánù tí ń wàásù títí di ìsinsìnyí ni ìjọba Ọlọ́run tí di àfi agbára wọ̀, àwọn ọkùnrin akíkanjú ní ń fí agbára gbàá.