adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/26.txt

1 line
316 B
Plaintext

\v 26 Nítorí náà, ẹ má bẹ̀rù wọn, nítorí kò sí ohun tí ó wà ní ìpamọ́ tí kò ní fara hàn, kò sì sí ohun àṣírí tí a kò ní mọ̀. \v 27 Ohun tí mo sọ fun yín níkọ̀kọ̀, ẹ sọ ọ́ ní gbangba, ohun tí ẹ gbọ́ ní ìdájẹ́jẹ́, ẹ kéde rẹ̀ lórí òrùlé.