adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/16.txt

1 line
504 B
Plaintext

\v 16 Wò ó, mo rán an yín jáde gẹ́gẹ́ bí àgùntàn láarín àwọn ìkokò, nítorínà ẹ gbọ́n bí àwọn ejò, kí ẹ sì jẹ́ aláìlúwu bí àwọn àdàbà. \v 17 Ẹ ṣọ́ra fún enìyàn! Nítorí wọn yóò jọ̀wọ́ yín fún àwọn ìgbìmọ̀, wọn á sì nà yín nínú Sínágọ́gù wọn. \v 18 Wọn á sì mú u yín wá sí ọ̀dọ àwọn Gómínà àti àwọn ọba nitorí tèmi, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí fún wọn àti fún àwọn kèfèrí