adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/14.txt

1 line
325 B
Plaintext

\v 14 Fún àwọn tí kò gbà yín tàbí tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ yín, nígbàtí ẹ bá kúrò ní ilé tàbí ìlú náà, ẹ gbọ́n iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ yín kúrò. \v 15 Lóǒtọ́ ni mo wí fún n yín, ó sàn fún ilẹ̀ Sódómù àti Gòmórà ní ọjọ́ ìdájọ́ jù fún ìlú náà.