adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/01.txt

1 line
229 B
Plaintext

\c 10 \v 1 Jésù pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ méjìlá papọ̀, ó sì fún wọn ní àsẹ lórí àwọn ẹ̀mí àìmọ́, láti lé wọn jáde, àti láti wo orísìrísìí àrùn ati onírúurú àìsàn sàn.