adesinaabegunde_yo_mat_text.../05/36.txt

1 line
340 B
Plaintext

\v 36Tàbí kí o jẹ́jẹ̀ẹ́ nípa orí rẹ, nítorí o kò lè mú ọ̀kan nínú irun orí rẹ funfun tàbí dúdú. \v 37 Ṣùgbọ́n jẹ́ kí 'bẹ́ẹ̀-ni rẹ jẹ́ bẹ́ẹ̀-ni' tàtí 'bẹ́ẹ̀-kọ́ bẹ́ẹ̀-kọ́.' Ohunkohun tó bá jù báyìí lọ láti ọ̀dọ̀ àwọn ẹni ibi ló ti wá.