adesinaabegunde_yo_mat_text.../03/13.txt

1 line
464 B
Plaintext

\v 13 Lẹ́yìn náà ni Jésù wá láti Gálílì si ọ̀dọ̀ Johánù ní Odò Jọ́dánì ki o leè baptisí rẹ̀. \v 14 Ṣùgbọ́n Johánù kọ̀ fún un, ó wípé, "Èmi ní o yẹ látii wá fún ìbaptisí lọ́dọ̀ rẹ, èése tí ìwó si fi tọ̀ mí wá?" \v 15 Jésù dáhùn o wi fun un pe, "Jọwọ̀ọ́ rẹ̀ bẹ́ẹ̀, o yẹ kí á mú gbogbo àwọn òfin sẹ béè. Bẹ́ẹ̀ni Jòhánù si gbà bẹ́ẹ̀ fún un.