\v 3 Ìrísí rẹ̀ dà bí iná, aṣọ rẹ̀ sì funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú \v 4 Àwọn ẹ̀ṣọ́ náà sì gbọ̀n jìnìjinì fún ẹ̀rù wọ́n sì dà bí òkú.