Wed May 15 2019 11:45:21 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-15 11:45:23 +01:00
parent 7384590a0d
commit f976d8a123
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Nígbàtí wọ́n ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ọba, wọ́n bá ọ̀nà ti won lọ, ìràwọ̀ tí wọ́n rí láti ìlà-oòrùn sì ń lọ níwájú wọ́n títí ó fi dúró ní ọ̀gángan ibi tí ọmọ ọwọ́ náà gbé wà. \v 10 Nígbàtí wọ́n rí ìràwọ̀ naa, won yo ayo nla gidigidi.
\v 9 Nígbàtí wọ́n ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ọba, wọ́n bá ọ̀nà ti won lọ, ìràwọ̀ tí wọ́n rí láti ìlà-oòrùn sì ń lọ níwájú wọ́n títí ó fi dúró ní ọ̀gángan ibi tí ọmọ ọwọ́ náà gbé wà. \v 10 Nígbàtí wọ́n rí ìràwọ̀ náà, wọ́n yọ̀ ayọ̀ ńlá gidigidi.

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Won wo inu ile, won si ri omo owo naa pelu Maria iya re. Won wole, won si fi ori bale, won si josin fun un. Won tu apo isura won lati fun un ni ebun wura, turari, ati ojia. \v 12 Olorun kilo fun won ni oju ala lati mase pada si odo Herodu, nitorina, won pada si orile-ede tiwon nipa ona ibomiran.
\v 11 Wọ́n wo inu ile, won si ri omo owo naa pelu Maria iya re. Won wole, won si fi ori bale, won si josin fun un. Won tu apo isura won lati fun un ni ebun wura, turari, ati ojia. \v 12 Olorun kilo fun won ni oju ala lati mase pada si odo Herodu, nitorina, won pada si orile-ede tiwon nipa ona ibomiran.