Thu May 16 2019 13:26:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 13:26:41 +01:00
parent 96cfd70a06
commit 89e96b561a
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Hẹ́rọ́dù si kó àwon olori àlùfáà àti àwọn akọ̀wé jọ, ó sì bi wọ́n léèrè wípé, "Níbo ni ó yẹ kí ìbí Krístì ti wáyé?" \v 5 Wọ́n wí fun un pé, "Ní Bẹ́thẹ́hẹ́mù ti Jùdíà ni, nítorí báyìí ni a ti kọ̀wé rẹ̀ láti ọwọ́ àwon Wòlíì pé, \v 6 'Sùgbọ́n ìwọ, Bẹ́thẹ́hẹ́mù, ní ilẹ̀ Júdà, kìí se èyí tí ó kéré jùlọ láàrin àwon adarí Júdà, nítorí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni alákoso tí yóò se olùsọ́-àgùntàn àwon ènìyàn Ísráẹ́lì.'
\v 4 Hẹ́rọ́dù si kó àwon olori àlùfáà àti àwọn akọ̀wé jọ, ó sì bi wọ́n léèrè wípé, "Níbo ni ó yẹ kí ìbí Krístì ti wáyé?" \v 5 Wọ́n wí fun un pé, "Ní Bẹ́thẹ́hẹ́mù ti Jùdíà ni, nítorí báyìí ni a ti kọ̀wé rẹ̀ láti ọwọ́ àwon Wòlíì pé: \v 6 'Sùgbọ́n ìwọ, Bẹ́thẹ́hẹ́mù, ní ilẹ̀ Júdà, ìwọ kò kéré jùlọ láàrin àwon c Júdà, nítorí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni alákoso tí yóò se olùsọ́-àgùntàn àwon ènìyàn Ísráẹ́lì.'