Tue May 14 2019 09:29:37 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 09:29:37 +01:00
parent 4b062f9f7b
commit 6cf9faf5de
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Sì wó, àwọn kan nínú àwọn akọ̀wé sọ láarín ara wọn pé, "Okùnrin yi ńsọ ọ̀rọ̀ òdì." \v 4 Jésù mọn àwọn èrò ọkàn wn o si wipe, "Kilode ti e fi nro ero ibi ninu okan yin? \v 5 Nje ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re."
\v 3 Sì wó, àwọn kan nínú àwọn akọ̀wé sọ láarín ara wọn pé, "Okùnrin yi ńsọ ọ̀rọ̀ òdì." \v 4 Jésù mọn àwọn èrò ọkàn wọn ó sì wípé, "Kílódé tí ẹ fi ńro èrò ibi nínú ọkàn yín? \v 5 Ǹjẹ́ èwó ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi pe, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo pe Omo Eniyan ni ase laye lati dari ese ji ni,... "o so fun aro na pe, "dide, gbe eni i re, ki o si ma lo si ile re."