diff --git a/09/10.txt b/09/10.txt index 597455e5..7012d97e 100644 --- a/09/10.txt +++ b/09/10.txt @@ -1 +1 @@ -\v 10 Bí Jésù ti jòkó láti jẹun nínú ilé, sì wó, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó orí àti ẹlẹ́ṣẹ̀ ènìyàn sí wàá, nwọ́n sì bá Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn (atele) rẹ̀ Jẹun. \v 11 Àwọn amòfin rí i, nwọ́n sọ fún àwọn ọmọ ẹyìn, "Kí ló dé tí Olùkọ́ yi njeun pelu awon agbowo ori ati elese eniyan?" \ No newline at end of file +\v 10 Bí Jésù ti jòkó láti jẹun nínú ilé, sì wó, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó orí àti ẹlẹ́ṣẹ̀ ènìyàn sí wàá, nwọ́n sì bá Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn (atele) rẹ̀ Jẹun. \v 11 Àwọn amòfin rí i, nwọ́n sọ fún àwọn ọmọ ẹyìn, "Kí ló dé tí Olùkọ́ yiń ńjẹun pẹ̀lú àwọn agbowó or ati elese eniyan?" \ No newline at end of file