Fri May 21 2021 14:18:55 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-21 14:18:55 +01:00
parent bf3753cc76
commit 5c9ce64327
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Fún àwọn tí kò gbà yín tàbí tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ yín, nígbàtí ẹ bá kúrò ní ilé tàbí ìlú náà, ẹ gbọ́n iyẹ̀pẹ̀ kúrò lẹ́sẹ̀ yín. \v 15 Òótọ́ ni mo wí fún n yín, ó sàn fún ilẹ̀ Sódómù àti Gòmórà ní ọjọ́ ìdájọ́ jù fún naa
\v 14 Fún àwọn tí kò gbà yín tàbí tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ yín, nígbàtí ẹ bá kúrò ní ilé tàbí ìlú náà, ẹ gbọ́n iyẹ̀pẹ̀ kúrò lẹ́sẹ̀ yín. \v 15 Òótọ́ ni mo wí fún n yín, ó sàn fún ilẹ̀ Sódómù àti Gòmórà ní ọjọ́ ìdájọ́ jù fún ìlú náà.

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Wo, mo ran yin jade gege bi aguntan larin awon ikoko, nitorina e gbon bi awon ejo, ki e si je alailewu bi awon adaba. \v 17 E se akiyesi awon eniyan! Nitori won a jo wo yin fun awon adajo, won a si na yin ninu awon Sinagogu won \v 18 Won a mu yin wa si odo awon Gomina ati awon Oba nitori te mi, gege bi eri fun won ati fun awon keferi.
\v 16 Wò ó, mo ran yin jade gege bi aguntan larin awon ikoko, nitorina e gbon bi awon ejo, ki e si je alailewu bi awon adaba. \v 17 E se akiyesi awon eniyan! Nitori won a jo wo yin fun awon adajo, won a si na yin ninu awon Sinagogu won \v 18 Won a mu yin wa si odo awon Gomina ati awon Oba nitori te mi, gege bi eri fun won ati fun awon keferi.

View File

@ -43,7 +43,6 @@
"10-05",
"10-08",
"10-11",
"10-16",
"10-21",
"10-24",
"10-26",