Wed May 26 2021 10:13:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 10:13:44 +01:00
parent ca3df47d50
commit 5a32af8ebc
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Nítorí Ọlọ́run wípé, 'Bọ̀wọ̀ fún bàbá àti ìyá rẹ,' àti pé 'Ẹni tí ó bá so búburú nípa bàbá tàbí ìyá rẹ̀, kíkú ni yíò kú. \v 5 Sùgbọ́n ẹ̀yín wípé, Ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ fún bàbá tàbí ìyá rẹ̀ wípé "ìrànwọ́ yìó wù tí ó yẹ kí ẹ̀yin ó rí gbà lí ọwọ́ mi ti di ẹ̀bùn fún Ọlọ́run,"' \v 6 kò yẹ kí ẹni bẹ́ẹ́ bu ọlá fún bàbá rè. nípa bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin ti sọ òfin Ọlọ́run di òfo nítorí ìse yín.
\v 4 Nítorí Ọlọ́run wípé, 'Bọ̀wọ̀ fún bàbá àti ìyá rẹ,' àti pé 'Ẹni tí ó bá so búburú nípa bàbá tàbí ìyá rẹ̀, kíkú ni yíò kú. \v 5 ùgbọ́n ẹ̀yín wípé, Ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ fún bàbá tàbí ìyá rẹ̀ wípé "ìrànwọ́ yìó wù tí ó yẹ kí ẹ̀yin ó rí gbà lí ọwọ́ mi ti di ẹ̀bùn fún Ọlọ́run,"' \v 6 kò yẹ kí ẹni bẹ́ẹ̀ bu ọlá fún bàbá a rè. Nípa bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin ti sọ òfin Ọlọ́run di òfo nítorí ìse yín.