diff --git a/26/23.txt b/26/23.txt index aa93c6e2..7079110f 100644 --- a/26/23.txt +++ b/26/23.txt @@ -1 +1 @@ -\v 23 Ó dáwọn lóhùn wípé, "Ẹniti yóò fi mí hàn ni ó ń jẹun pẹ̀lú mi nínú igbá kannáà" \v 24 Ọmọ ènìyàn yóò kọjá lọ gẹ́gẹ́ bí ati kọọ́ sílẹ̀ nípa Rẹ̀. Ṣùgbọ́n ègbé ni fún arákùnrin náà, tí ó da ọmọ ènìyàn! Kò bá sàn kí ìyá rẹ̀ má bíi. \v 25 Júdásì, ẹniti yóò fií hàn bèèrè pé, "Olùkọ́ni, sé èmi ni bí?" Ó sì dáà lóhùn pé, "Ìwọ fúnra rẹ ti dáhùn" \ No newline at end of file +\v 23 Ó dáwọn lóhùn wípé, "Ẹniti yóò fi mí hàn ni ó ń jẹun pẹ̀lú mi nínú igbá kan náà" \v 24 Ọmọ ènìyàn yóò kọjá lọ gẹ́gẹ́ bí ati kọọ́ sílẹ̀ nípa Rẹ̀. Ṣùgbọ́n ègbé ni fún arákùnrin náà, tí ó da ọmọ ènìyàn! Kò bá sàn kí ìyá rẹ̀ má bíi. \v 25 Júdásì, ẹniti yóò fií hàn bèèrè pé, "Olùkọ́ni, sé èmi ni bí?" Ó sì dáà lóhùn pé, "Ìwọ fúnra rẹ ti dáhùn" \ No newline at end of file diff --git a/26/36.txt b/26/36.txt index 38f2c418..6fe45e5d 100644 --- a/26/36.txt +++ b/26/36.txt @@ -1 +1 @@ -\v 36 Nígbà náà ni Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí ibi tí a ń pè ní Gẹ́símánì. Ó sì sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wípé, "Ẹ jókòó sí ibíìyí, Nígbàtí èmi yóò lọ síwájú síi láti gbàdúrà." \v 37 Ó mú Pétérù àti àwọn ọmọ Sébédè méjèjé pẹ̀lú rẹ̀, inú rẹ̀ bàjẹ́ ọkàn rẹ̀ pòruùrú. \v 38 Nígbànáà ni Ó sọ pé, "Ẹ̀mí mi gbọgbé gidi gan, títí dé ojú ikú. Ẹdúró sí ibí yìí, kí ẹ sì máa bá mi sọ́nà." \ No newline at end of file +\v 36 Nígbà náà ni Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí ibi tí a ń pè ní Gẹ́símánì. Ó sì sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wípé, "Ẹ jókòó sí ibíìyí, Nígbàtí èmi yóò lọ síwájú síi láti gbàdúrà." \v 37 Ó mú Pétérù àti àwọn ọmọ Sébédè méjèjé pẹ̀lú rẹ̀, inú rẹ̀ bàjẹ́ ọkàn rẹ̀ pòruùrú. \v 38 Nígbà náà ni Ó sọ pé, "Ẹ̀mí mi gbọgbé gidi gan, títí dé ojú ikú. Ẹdúró sí ibí yìí, kí ẹ sì máa bá mi sọ́nà." \ No newline at end of file