Tue May 11 2021 13:24:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
FolashadeOloyede 2021-05-11 13:24:34 +01:00
parent d1e82118c8
commit 4e5fc1b3b7
9 changed files with 9 additions and 45 deletions

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 3 Nígbà tí ó di òwúrọ̀, ẹ̀yin wípé, 'ojú ọjọ́ yóó dára, nítorí ojú ọ̀run pọ́n ó sì sú dẹdẹ. Ẹ̀yin mọ bí a tí ń túmọ̀ àmì ojú ọ̀run, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò mọ bí a tí ń túmọ̀ àmì àkókò. \v 4 Ìran búburú àtí panságà ń wá àmì kan, ṣùgbọ́n a kì yío fún n ní àmì bíkòse ti Jónà." Jésù si fi wọ́n sílẹ̀ ó sì kúrò níbẹ̀.
=======
\v 3 Nígbàtí ilẹ̀ bá mọ́, ẹ̀yin yio wípé, ọjọ́ kò dára, nítorí ti ojú ọ̀run pupa ó sú dẹ̀dẹ̀. Ẹ̀yin mọ àmì ojú ọrun, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ko mọ àmì àkókò wọ̀nyí. \v 4 Ìran búburú ati pansaga n fẹ́ àmì, ṣùgbọ́n ko si àmì fun yin bíkòsè àmì Jónà. Jesu fi wọ́n silẹ, O si kúrò nibẹ.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 3 Nígbà tí ó di òwúrọ̀, ẹ̀yin wípé, 'ojú ọjọ́ yóó dára, nítorí ojú ọ̀run pọ́n ó sì sú dẹdẹ. Ẹ̀yin mọ bí a tí ń túmọ̀ àmì ojú ọ̀run, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò mọ bí a tí ń túmọ̀ àmì àkókò. \v 4 Ìran búburú àtí panságà ń wá àmì kan, ṣùgbọ́n a kì yío fún n ní àmì bíkòse ti Jónà." Jésù si fi wọ́n sílẹ̀ ó sì kúrò níbẹ̀.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 5 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn dé òdì kejì, wọ́n ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. \v 6 Jésu wí fún wọn, "Ẹ kíyèsára kí ẹ sì máa sọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí." \v 7 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí bá ara wọn sọ̀rọ̀ wọ́n sì wípé, "Nítorípé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni." \v 8 Jésù si mọ èyí ó sì wípé, "èyin onígbàgbọ́ kékeré, kí lódé tí ẹ̀yin fi ń bá ara yín sọ̀rọ̀ wípé nítorí àwa kò mú ákàrà lọ́wọ́ ni?
=======
\v 5 Nigbàtí àwọn ọmọ-ẹhin Rẹ si de apákejì, wọn ti gbàgbé lati mu bùredí lọ́wọ́. \v 6 Jesu wi fun wọn pe, Ẹ kíyèsára , ki ẹ si sọra niti àiwúkárá àwọn Farisi ati àwọn Sadusi. \v 7 Wọn si n ba ara wọn sároyé wipe, Nitórí àwa kò mú bùredí lọwọ́ ní. \v 8 Jesu wòye O si wi fun wọn pé, ẹ̀yin onígbàgbọ́ kékeré, ki ló dé ti ẹ̀yin fi n bá ara yin sároyé nitórí ẹyin kò mú bùredí lọwọ?
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 5 Nígbàtí àwọn ọmọ ẹ̀yìn dé òdì kejì, wọ́n ti gbàgbé láti mú àkàrà lọ́wọ́. \v 6 Jésu wí fún wọn, "Ẹ kíyèsára kí ẹ sì máa sọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí." \v 7 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí bá ara wọn sọ̀rọ̀ wọ́n sì wípé, "Nítorípé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni." \v 8 Jésù si mọ èyí ó sì wípé, "èyin onígbàgbọ́ kékeré, kí lódé tí ẹ̀yin fi ń bá ara yín sọ̀rọ̀ wípé nítorí àwa kò mú ákàrà lọ́wọ́ ni?

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 9 Kò tí yé yín di ìsinsìnyí tàbí ẹ̀yin kó rántí ìsù àkàrà márǔn fún àwọn ẹgbèrún márǔn nì, àti iye agbọ̀n tí ẹ̀yin sì kó jọ? \v 10 Tàbí ìsù àkàrà méje fún àwọn ẹgbèrún mérin, àti iye agbọ̀n tí ẹ̀yin kó jọ?
=======
\v 9 Sé kò yé yín tabi ẹ̀yin ko rántí búrẹ́dì máárùn fun ẹgbẹẹdọgbọn ènìyaìn ati iye agbọ̀n ti ẹ̀yin sí kójọ \v 10 Tàbí bùredí mééje ti ẹgbàajì èniyan jẹ́ ati iye agbọ̀n ti o sẹkù?
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 9 Kò tí yé yín di ìsinsìnyí tàbí ẹ̀yin kó rántí ìsù àkàrà márǔn fún àwọn ẹgbèrún márǔn nì, àti iye agbọ̀n tí ẹ̀yin sì kó jọ? \v 10 Tàbí ìsù àkàrà méje fún àwọn ẹgbèrún mérin, àti iye agbọ̀n tí ẹ̀yin kó jọ?

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 11 Báwo ni kò se yé yín pé èmi kò bá yín sọ̀rọ̀ nípa ti àkàrà? "Ẹ kíyèsára kí ẹ sì máa ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí". \v 12 Nígbà náà ni ó yé wọn pé kò bá wọn sọ̀rọ̀ nípa ti ìwúkàrà ti àkàrà, ṣùgbọ́n kí wọ́n sọ́ra fún ẹ̀kọ́ àwọn Farisí àti Sadusí.
=======
\v 11 Ki lò dé ti kò ye yín wipe Emí kò sọrọ̀ nípa bùredí, ẹ kíyèsára yin niti ìwúkàrà àwọn Farisi ati àwọn Sadusi. \v 12 Lẹyin naa ni o tó yé wọn pe, ki i se ìwúkàrà ti àkàrà ni o n sọ, ṣùgbọ́n ki wọn ki o kíyèsára fun ẹ̀kọ́ àwọn Farisi ati àwọn Sadusi.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 11 Báwo ni kò se yé yín pé èmi kò bá yín sọ̀rọ̀ nípa ti àkàrà? "Ẹ kíyèsára kí ẹ sì máa ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti Sadusí". \v 12 Nígbà náà ni ó yé wọn pé kò bá wọn sọ̀rọ̀ nípa ti ìwúkàrà ti àkàrà, ṣùgbọ́n kí wọ́n sọ́ra fún ẹ̀kọ́ àwọn Farisí àti Sadusí.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 13 Nígbàtí Jésù dé ìgbèríko tí ó súnmọ́ Kesaréà Fílíppì, ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lěrè, wípé, Tali àwọn ènìyàn ń fi Ọmọ Ènìyàn pè? \v 14 Nwọ́n sì wí fún u pé, "Òmíràn ní, Johanu Baptisti; òmíràn wípé, Elijah; àwọn ẹlòmíràn ní, Jeremiah, tàbí ọ̀kan nínú àwọn wòólì. \v 15 Ó bi wọ́n lêrè, wípé, Ṣùgbọ́n tali ẹ̀yin ńfi mí pè? \v 16 Símónì Pétérù si dáhùn, wípé, ìwọ ni Krístì, Ọmọ Ọlọ́run alààyè.
=======
\v 13 Nísinsin-ìnyí, nigbàtí Jesu de agbègbè Kasaríà Filipi, O bi àwọn ọmọ-ẹyin Rẹ́ leere wipé, Kini àwọn enìyàn n fi Èmi Ọmọ Eniyan pe? \v 14 Wọn daa lohun wipé, "àwọn kan ni Johanu onitebomi, bẹẹ gẹ́gẹ́ ni àwọn miran wipé Elija, àwọn ẹlòmíràn wipé Jeremáyà tabi ọ̀kan ninu àwọn wolii" \v 15 O bí wọ́n leere wipé, "Sùgbọn tani ẹ̀yin n fí mí pè? \v 16 Nigbà naa ní Simoni Peteru dáá lohun wipé, Kristi, Ọmọ Ọlọrun alàayè ni Ìwọ jẹ.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 13 Nígbàtí Jésù dé ìgbèríko tí ó súnmọ́ Kesaréà Fílíppì, ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lěrè, wípé, Tali àwọn ènìyàn ń fi Ọmọ Ènìyàn pè? \v 14 Nwọ́n sì wí fún u pé, "Òmíràn ní, Johanu Baptisti; òmíràn wípé, Elijah; àwọn ẹlòmíràn ní, Jeremiah, tàbí ọ̀kan nínú àwọn wòólì. \v 15 Ó bi wọ́n lêrè, wípé, Ṣùgbọ́n tali ẹ̀yin ńfi mí pè? \v 16 Símónì Pétérù si dáhùn, wípé, ìwọ ni Krístì, Ọmọ Ọlọ́run alààyè.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 17 Jésù dáhùn ó sì wí fún pé, Alábùkúnfún ni ìwọ Símónì Ọmọ Jona, nítorí kìí ṣe ẹran ara àti ẹ̀jẹ̀ ni ó fi èyí hàn ọ́, ṣùgbọ́n Baba mi tí ḿbẹ lí ọ̀run. \v 18 Èmi sì wí fún ọ pẹ̀lú pé ìwọ ni Pétérù, orí àpáta yí ni èmi yó kọ́ ìjọ mi lé pẹ̀lú. Ẹnu ọ̀nà ipò òkú kì yóò sì le borí rẹ̀.
=======
\v 17 Jésù dáa loóhùn wipe, ìbùkún ni fun ìwọ Simoni ọmọ Jona, nítorí kii se ẹran ara ati ẹ̀jẹ̀ ló fí hán ọ bi kose Bàbá mi ti n bẹ ni ọrun \v 18 Emi si tun wi fun ọ pe, ìwọ ni Peteru, lori òkúta yi ni Emi yio kọ ijọ mi le, ilẹkun ọrun apaadi ki yio le bori rẹ.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 17 Jésù dáhùn ó sì wí fún pé, Alábùkúnfún ni ìwọ Símónì Ọmọ Jona, nítorí kìí ṣe ẹran ara àti ẹ̀jẹ̀ ni ó fi èyí hàn ọ́, ṣùgbọ́n Baba mi tí ḿbẹ lí ọ̀run. \v 18 Èmi sì wí fún ọ pẹ̀lú pé ìwọ ni Pétérù, orí àpáta yí ni èmi yó kọ́ ìjọ mi lé pẹ̀lú. Ẹnu ọ̀nà ipò òkú kì yóò sì le borí rẹ̀.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 19 Èmi ó sì fún ọ ní kọ́kọ́rọ́ ìjọba ọ̀run. Ohunkóhun tí ìwọ bá dè lí aiyé a ó sì dè é lí ọ̀run, ohunkóhun tí ìwọ bá tú sìlẹ̀ li aiyé a ó tu sílẹ̀ lí ọ̀run. \v 20 Jésù sí pàsẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn kí wọ́n má se sọ fún ẹnikẹ́ni wípé òhun ni Krístì.
=======
\v 19 Emi yio fun ọ ni kọkọrọ ijọ́bá ọrún, ohunkohun ti iwọ ba de ni aye, a o si dee ni ọrun: ohunkohun ti iwọ́ ba tu ni aye, a o si tu ni ọrun \v 20 Lẹyin na, O pasẹ fun awọn ọmọ ẹyin Rẹ pe, wọn ko gbọdọ̀ sọ fun ẹnikan pe, Oun ni kristi.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 19 Èmi ó sì fún ọ ní kọ́kọ́rọ́ ìjọba ọ̀run. Ohunkóhun tí ìwọ bá dè lí aiyé a ó sì dè é lí ọ̀run, ohunkóhun tí ìwọ bá tú sìlẹ̀ li aiyé a ó tu sílẹ̀ lí ọ̀run. \v 20 Jésù sí pàsẹ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn kí wọ́n má se sọ fún ẹnikẹ́ni wípé òhun ni Krístì.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 21 Láti ìgbànáà lọ ni Jésu ti bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wípé òun gbọdọ̀ lọ sí Jerúsálẹ̀mù, láti jẹ ọ̀pọ̀ ìyaà lọ́wọ́ àwọn àgbàgbà àti àwọn olórí àlùfâ, àti àwọn akọ̀wé, kí a sì pa òun, àti ní ọjọ́ kẹta, kí òun sí jí dìde. \v 22 Nígbànâ ni Pétérù mu u sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bá a wí pé, "Kí á má ri i, Olúwa, kì yóò rí bẹ̃ fún ọ. \v 23 Ṣùgbọ́n ó yípadà, ó sì wí fún Pétérù pé, "Kúrò lẹ́yìn mi, Sátánì! Ohun ìkọ̀sẹ̀ ni ìwọ jẹ́ fún mi, nítorí ìwọ kò ro ohun tí i ṣe ti Ọlọ́run, bíkòṣe èyí tí í ṣe ti ènìyàn.
=======
\v 21 Lati àkókò naa lọ ni Jesu ti bẹ̀rẹ̀ si ni sọ fun awọn ọmọ-ẹyin Rẹ wipe, Oun gbọdọ̀ lọ si Jerusalemu, lati lọ jẹ ọ̀pọ̀ iya lọwọ awọn àgbàagbà ati awọn olori alufa, ati awọn akọwé, ki a si pa Oun ati ni ọjọ́ kẹ̀ta, ki Oun o si jinde. \v 22 Nigba naa ni Peteru mu un lọ si ẹgbẹ́kan, o wi fun un pe, "ki a ma ri i Oluwa, ki yio ri bẹ fun ọ." \v 23 Ṣugbọn Jesu yipada, O si wi fun Peteru wipe, pada kuro lẹyin mi Satani, ohun ikọsẹ̀ ni o jẹ fun mi, ìwọ ko bikita fun ohun ti se ti Ọlọrun bikose ohun ti se ti eniyan.
>>>>>>> a39fe5f668c5287ccb9d6480672c790f024d3237
\v 21 Láti ìgbànáà lọ ni Jésu ti bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wípé òun gbọdọ̀ lọ sí Jerúsálẹ̀mù, láti jẹ ọ̀pọ̀ ìyaà lọ́wọ́ àwọn àgbàgbà àti àwọn olórí àlùfâ, àti àwọn akọ̀wé, kí a sì pa òun, àti ní ọjọ́ kẹta, kí òun sí jí dìde. \v 22 Nígbànâ ni Pétérù mu u sí ẹ̀gbẹ́ kan ó sì bá a wí pé, "Kí á má ri i, Olúwa, kì yóò rí bẹ̃ fún ọ. \v 23 Ṣùgbọ́n ó yípadà, ó sì wí fún Pétérù pé, "Kúrò lẹ́yìn mi, Sátánì! Ohun ìkọ̀sẹ̀ ni ìwọ jẹ́ fún mi, nítorí ìwọ kò ro ohun tí i ṣe ti Ọlọ́run, bíkòṣe èyí tí í ṣe ti ènìyàn.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 24 Nígbànáà ni Jésu wí fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, " Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tẹ̀lé mi, ó gbọ́dọ̀ sé ara rẹ̀, kí ó gbé ǎgbélébǔ rẹ̀, kí ó sì tèlé mi. \v 25 Nítorí ẹni tí ó bá fẹ́ gba ẹ̀mí rẹ là yóó sọ ọ́ nù, àti ẹni tí ó bá sọ ẹ̀mí rẹ nù nítorí mi yó ri. \v 26 Nítorí àǹfàní kí ni ó jẹ́ fún ènìyàn tí ó bá jèrè gbogbo ayé tí ó sì sọ èmí rẹ̀ nù? Kíni yí ó fì se pàsí pàrọ̀ ẹ̀mí rẹ̀?
=======
\v 24 Lẹyin na ni Jesu sọ fun awọn ọmọ ẹyin Rẹ pe, bi ẹnìkán ba fẹ lati tẹ̀lémi, ki o sẹ ara rẹ, ki o si gbe àgbelébú rẹ, ki o si maa tele mi. \v 25 Nitori, ẹni ti o ba fẹ gba ẹmí rẹ la, yio sọọ nu, sugbọn ẹni ti o ba sọ ẹmi rẹ nu nitori mi yio ri i \v 26 Nitori ere kini fun eniyan, ti o jere gbogbo ayé ti o si padánù ẹmí rẹ tabi kini yio fi parọ̀ ẹmí rẹ.