Fri May 21 2021 15:18:55 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-21 15:18:55 +01:00
parent 85b3ba55a4
commit 3df5949b5b
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 37 Ẹnití ó bá fẹ́ràn baba tabi ìyá rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi; ẹni tí ó bá sì fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ ọkunrin tabi obinrin jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi. 38Bẹ́ẹ̀ ni, ẹnikẹ́ni tí kò bá gbé agbelebu rẹ̀, kí ó máa tẹ̀lé mi, kò yẹ ní tèmi. 39Ẹni tí ó bá sì fẹ́ gba ẹ̀mí rẹ̀ là yóo pàdánù rẹ̀; ṣugbọn ẹni tí ó bá pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ nítorí mi yóo jèrè rẹ̀.\v 38 Eni ti ko ba ti gbe agbelebu re ki o si ma tele mi ko ye niti temi. \v 39 Eni ti o ba wa aye re ri yio sonu. Sugbon eni ti o ba so aye re nu nitori temi yio ri.
\v 37 Ẹnití ó bá fẹ́ràn baba tabi ìyá rẹ̀ jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi; ẹni tí ó bá sì fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ ọkunrin tabi obinrin jù mí lọ, kò yẹ ní tèmi. \v 38 Ẹni tí kò bá gbé agbelebu rẹ̀, kí ó máa tẹ̀lé mi, kò yẹ ní tèmi. \v 39 Ẹni tí ó bá gba ẹ̀mí rẹ̀ là yóo pàdánù rẹ̀. Sùgbọn ẹni tí ó bá pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ nítorí mi yíó rí i.