Wed May 26 2021 10:23:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-26 10:23:44 +01:00
parent 02abe902a3
commit 3ab650a9ee
4 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 32 Jésù si pe àwọn ọmọẹyìn rẹ̀ sí ọdọ̀ rẹ̀ ó wípé, " Àánú ọ̀pọ̀ enìyàn yí se mí, nitorí wọ́n ti dúró tì mí fún ọjọ́ mẹ́ta wọn kò sì ní ohun láti je. Èmi kò fé rán wọn lọ láì jẹun, kí àárẹ̀ má baà mú wọn ní ọnà." \v 33 A'wọn ọmọ ẹyìn siwí fún n pé, "Níbo li a ó ti rí akàrà tí yíò tó ní aginjù yí tí yíò bọ́ ọpọ̀ erò yí?" \v 34 Jésù wí fún wọn pé, "ìsù akàrà mélǒ nió wà? Wọ́n wípé, "Méje, àti eja wẹ́wẹ́ díè." \v 35 Jésù si pàsẹ kí ọ̀pọ̀ enìyàn náà jókǒ sílẹ̀.
\v 32 Jésù si pe àwọn ọmọẹyìn rẹ̀ sí ọdọ̀ rẹ̀ ó wípé, "Àánú ọ̀pọ̀ enìyàn yí se mí, nitorí wọ́n ti dúró tì mí fún ọjọ́ mẹ́ta wọn kò sì ní ohun láti je. Èmi kò fé rán wọn lọ láì jẹun, kí àárẹ̀ má baà mú wọn ní ọnà." \v 33 Àwọn ọmọ ẹyìn siwí fún n pé, "Níbo li a ó ti rí akàrà tí yíò tó ní aginjù yí tí yíò bọ́ ọpọ̀ erò yí?" \v 34 Jésù wí fún wọn pé, "Ìsù akàrà mélǒ nió wà? Wọ́n wípé, "Méje, àti eja wẹ́wẹ́ díè." \v 35 Jésù si pàsẹ kí ọ̀pọ̀ enìyàn náà jókǒ sílẹ̀.

View File

@ -1 +1 @@
\v 36 Ó sì mú ìsù akàrà méje àti ẹja náà, nígbà tí ó sì ti dúpẹ́, ó bu akàrà náà ó sì fún àwọn ọmọ ẹyìn. Àwọn ọmọ ẹyìn si fún àwọn ọpọ̀ enìyàn. \v 37 GBogbo wọ́n sì jẹ ẹ́ wọ́n sì yó. Wọ́n sì kó apẹ̀rẹ̀ méjé jọ tí óún fún àjẹkù. \v 38 Àwọn tí ó sì jẹ oúnjẹ náà jẹ́ ẹgbàájì okùnrin, yàtọ̀ sí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé. \v 39 Jésù si rán ọ̀pọ̀ enìyàn náà lọ ó sì bọ́ sínú ọkọ̀, ó sì lọ sí ẹ̀kún Màgádàn.
\v 36 Ó sì mú ìsù akàrà méje àti ẹja náà, nígbà tí ó sì ti dúpẹ́, ó bu akàrà náà ó sì fún àwọn ọmọ ẹyìn. Àwọn ọmọ ẹyìn si fún àwọn ọpọ̀ enìyàn. \v 37 Gbogbo wọ́n sì jẹ ẹ́ wọ́n sì yó. Wọ́n sì kó apẹ̀rẹ̀ méjé jọ tí óún fún àjẹkù. \v 38 Àwọn tí ó sì jẹ oúnjẹ náà jẹ́ ẹgbàájì okùnrin, yàtọ̀ sí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé. \v 39 Jésù si rán ọ̀pọ̀ enìyàn náà lọ ó sì bọ́ sínú ọkọ̀, ó sì lọ sí ẹ̀kún Màgádàn.

View File

@ -1 +1 @@
Orí ìkẹẹ̀dógún
Orí Kẹẹ̀dógún

View File

@ -67,6 +67,7 @@
"15-24",
"15-27",
"15-29",
"15-32",
"15-36",
"19-title",
"19-01",