Tue May 11 2021 14:10:17 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
FolashadeOloyede 2021-05-11 14:10:18 +01:00
parent 15a5c19372
commit 340f2b0f26
4 changed files with 5 additions and 4 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 32 Bí wón se dé ìta, ni wón rí ọkùnrin kan ará kírénì tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Símónì,wón fipá mú kí ó le tẹ̀lé won láti gbé àgbélèbú Jésù. \v 33 \v 34 Wón mu wá sí ibìkan tó ǹjẹ́ gọ́ngọ́ntà,èyí tí ìtumò rẹ̀ ni"ibi agbárí,"34 Wón fún ní ọtí tókorò mu tí wón ti fi òróǹro sí.sùgbón nígbàtí ómuń,ókorò kò le mú.
\v 32 Bí wón se dé ìta, ni wón rí ọkùnrin kan ará kírénì tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Símónì,wón fipá mú kí ó le tẹ̀lé won láti gbé àgbélèbú Jésù. \v 33 Wón mu wá sí ibìkan tó ǹjẹ́ gọ́ngọ́ntà,èyí tí ìtumò rẹ̀ ni"ibi agbárí," \v 34 Wón fún ní ọtí tókorò mu tí wón ti fi òróǹro sí. Sùgbón nígbàtí ómuń,ókorò kò le mú.

View File

@ -1 +1 @@
\v 36 \v 37 \v 35 Nígbàtí wón ti pá tán, wón pín asọ rẹ̀ nípa ìbò dídì,36 wón wá jòkó wón ń sọ́ọ.37Ní ibi orí rẹ̀ wón kọ àkọlé kan síbẹ,pé"èyí ni Jésù ọba àwon juu."
\v 35 Nígbàtí wón ti pá tán, wón pín asọ rẹ̀ nípa ìbò dídì, \v 36 wón wá jòkó wón ń sọ́ọ. \v 37 Ní ibi orí rẹ̀ wón kọ àkọlé kan síbẹ,pé"èyí ni Jésù ọba àwon juu."

View File

@ -1,2 +1,2 @@
\v 39 \v 40 \v 38 olè méjì ni wón kàn mó àgbélebú pẹ̀lú rẹ̀,ọ̀kan wà ní apá ọ̀tún àti ọ̀kan ní
\v 40 \v 38 olè méjì ni wón kàn mó àgbélebú pẹ̀lú rẹ̀,ọ̀kan wà ní apá ọ̀tún àti ọ̀kan ní
apá òsì rẹ̀.39 Gbogbo àwon tó ńkọjá lọ fise ẹléyà,wón sí ń min orí fu .40 wón ńwípé,"ìwọ ẹni tí yò wó tẹ́mpìlì tí yò sì tunkọ́ fún ọjọ́ mẹ́ta,gba aràrẹ là.tó bá jẹ pé ọmọ Ọlórun ni Ọ,sọ̀kalẹ̀ wá kúrò lórí àgbélèbú!"

View File

@ -403,7 +403,8 @@
"27-25",
"27-27",
"27-30",
"27-38",
"27-32",
"27-35",
"27-41",
"27-43",
"27-45",