Wed Nov 27 2019 13:16:25 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-27 13:16:26 -08:00
commit 32f89fabeb
21 changed files with 76 additions and 0 deletions

1
24/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 1 Jésù sì jáde kúrò nínú tempili ó sì ń lọ ní ọ̀nà tirẹ̀. Awọ̀n ọmọ ẹ̀yìn rẹ sí tọ́ wà láti fi àgọ́ tempili hán. \v 2 Ṣùgbọ́n ó dá wọn lóhuǹ ósì wípé, " Ẹ̀yin kò a rí nǹkan wọ̀nyí? Lótìítọ́ ni mo sọ fún yin, kò sí òkuta kan tí yíó wà lórí èkejí tí a kì yíò bì ṣubú."

1
24/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Bí ò sìti jókò ní orí òkè ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sí tọ́ wà ní ìkọ̀kọ̀ wọ́n sì wípé, "Sọ fún wa ìgbà wo ti nǹkan wọ̀nyí o ṣẹlẹ̀? kíni yíò jẹ́ àmìn bíbọ̀ rẹ àti òpin ìkẹyìn?" \v 4 Jésù sì dáhùn ósì wí fún wọn pé, Ẹ kíyèsara kí ẹnikẹ́ni mà ba ṣì yín darí. \v 5 Nítorí ọ̀pọ̀ yíò wá ní orúkọ mi. Wọn a sì wípé, "Èmi ni Kristi", wọn a sì ṣi ọ̀pọ̀ ènìyàn darí.

1
24/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 nítorí gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni yíò ṣẹlẹ́, ṣùgbọ́n òpin kò tíì dé. \v 7 Nítorí orílẹ́ èdè yíò dìde sí orìlẹ́ èdè, àti ìjọba sí ìjọba. Ìyàn yíò mún àti ilẹ̀ mínmìn ní ibi gbogbo. \v 8 Ṣùgbọ́n gbogbo nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ìpọ́njú.

1
24/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Bẹ́ẹ̀ni a ó fà yín fún ìpọ́njú a ó sì pa yín. Gbogbo orílẹ̀ èdè yíò kórira yín nítorí orúkọ mi. \v 10 Bẹ́ẹ̀ni ọ̀pọ̀ ènìyàn yíò ṣubú, wọn ó sì dalẹ́ ara wọn bẹ́ẹ̀ni won oó sì kórira ara wọn. \v 11 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ wòlíì ni yíò dìde wọn ó sì ṣi ọ̀pọ̀lọpọ̀ darí.

1
24/12.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 12 Nítorí àidédé yíò di púpọ̀, ìfẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ á sì tutù. \v 13 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá forítî ni a ó gbàlà. \v 14 ìyìnrere ìjọba yíò yí ni a ó wàásù ká gbogbo ayé gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí fún gbogbo orílẹ̀ èdè. Nígbànâ ni òpin yíò dé.

1
24/19.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 19 Ṣùgbọ́n ẹ̀gbé ni fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú ọmọ àti àwọn tí ó n tọ́ju ọmọ ọwọ́ ní ọjọ́ yìí. \v 20 \v 21 Nítorí ìpọ́njú ńlá yìó wà, èyí tí kò sẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé títí di ìsisìnyí, tí, kò sì sí èyí tí yíò dàbí rẹ̀ láí. \v 22 Àfi tí a bá fa àkókò nâ sẹ́yìn, kò sí o n kan tí yíò yè, ṣùgbọ́n nitorí àwọn àyànfẹ́, a ó fa àkókò nâ sẹ́yìn.

1
24/23.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 23 Nítorínâ tí ẹnìken bá wí fún yín pé, 'Wo Kristi wà ní ibíyî!' tàbí 'Ní ọ̀ún ni Kristi wà' ẹmá ṣe gbàgbọ́ \v 24 Nítorí Kristi èké àti wòlî èké yíò wà wọn ó sì fi isẹ́ àmì àti isẹ́ ìyanu hàn, kí wọn ó lè bà mú ni ṣìnà, bí ó bá ṣéṣe, àwọn àyànfẹ́. \v 25 Wô, èmí sọ fún yín ṣájú àkókò nâ.

1
24/26.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 26 Nítorínà, tí wọ́n bá sọ fún yín pé, 'Wô, ó wà ní ijù'. Tàbí, 'Wô, ó wa ní yàrá òkè,' ẹmá ṣe gbà wọ́n gbọ́. \v 27 Nítorí bí ìtànná ṣe tàn láti ìlà oòrùn dé ìwọ̀ oòrùn, bẹ́ẹ̀ni dídé ọmọ ènìyàn yíò rí. \v 28 Nítorí níbi tí òkú ẹranko gbéwà ni igúnnungún a máa péjọ si.

1
24/29.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 29

1
24/30.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 30 Nígbànâ ni àmà ọmọ ènìyàn yíò hàn nì àwọn sánmọ̀, bẹ́ẹ̀ni gbogbo ẹ̀yà ní orílẹ́ ayé yíò sọ̀fọ̀. Wọ́n ó rí ọmọ ènìyàn tí ó ń bọ̀ ní àwọ̀ sánmọ̀ pẹ̀lú agbára àti ógo ńlá. \v 31 Yíò rán àwọn ángélì rẹ̀ pẹ̀lú ariwo ìpè ńlá, wọ́n ó sì kó àwọn àyàfẹ́ jọ láti orígun mẹ́rẹ̀rin, láti òpin kan dé èkeji.

1
24/32.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 32 Ẹ kọ́ ẹ̀kọ́ láti ara igi ọ̀pọ̀tọ́. Nígbàtí ẹ̀ka rẹ̀ bá yọ titun tí ó bá sì rúwé, ẹ̀yín ó mọ̀ pé ẹ̀rùn súnmọ́ atílé. \v 33 Bákannâ pẹ̀lú, nígbàtí ẹbá rí nǹkan wọ̀nyí, kí ẹ̀yin kí ó mọ̀ pe òhún súnmọ́ etílé tán, ní ẹnu ìlẹ̀kùn.

1
24/34.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 34 Lótìtọ́ọ́ ni mo wi fún yín, ìran yî kì yíò lọ títí tí nńkan wọ̀nyí yíò fi sẹlẹ̀. \v 35 Ọ̀run àti ayé yíò kọjálọ ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ mi kì yíò kọjá lọ.

1
24/36.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 36 Ṣùgbọ́n nípa ìgba àti àkókò kò sí ẹni tí ó mọ́, àwọn angẹli ti ọ̀run kò tilẹ̀ mọ́, tábì ọmọ, bí kò ṣe Baba nìkan.

1
24/37.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 37 Bíi ọjọ́ Noaha ti wá, bệni dídé ọmọ ènìyàn. \v 38 Bí ó ti rí sáju ìkun omi wọ́n ń jẹ wọ́n sì ń mun, wọ́n ń gbéyàwó bêni à ń fa ìyàwó fún ni títí ọjọ́ tí Noaha fi wọ inú ọkọ̀, \v 39 wọ́n kò sì mọ ohun kó hun títí ìkún omi fi dé tí ó si gbé wọn lọ- bệni díde ọmọ ènìyàn yíò rí.

1
24/40.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 40 Nígbànâ ni okùnrin meji yíò wa lórí pápá- a ó mú ọ̀kan, a ó sì fi èkejì sílẹ̀. \v 41 Obìrin méjì yíò ma lọ̀ pẹ̀lú ònlọ̀- a ó mú ọ̀kan, a ó sì fi èkejì sílẹ̀. \v 42 Nítorínâ ẹ má ṣọ́nà, nítorí ẹ̀yín kò mọ ìgbà tí olúwa yín yíò dé.

1
24/43.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 43 Sugbon mo eyi, pe ti oluwa ile n a ba mo siko ti ole yio wa ni ale, o n iba si ti so na ki aba ko ile re. \v 44 Nitorinan e gbodo wani imura sile, nitori omo eniyan yio de ni wakati ti eyin ko mo

1
24/45.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 45 Nitorina tani oloto ati ologbon omo odo na ti olowa re yio fi se alakoso ile re lati ma fun won ni ounje ni asiko ti o ye? \v 46 Ibukun ni fun omo odo nan ti oluwa re ba ti o n se won nogbati o ba de. \v 47 Lotito ni mo wi fun yin pe oluwa re yio fi se olori gbogbo hun ti o ni.

BIN
24/48.txt Normal file

Binary file not shown.

29
LICENSE.md Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
# License
## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0)
This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/.
### You are free to:
* **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format
* **Adapt** — remix, transform, and build upon the material
for any purpose, even commercially.
The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms.
### Under the following conditions:
* **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work.
* **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original.
**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits.
### Notices:
You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation.
No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material.
This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/).

1
front/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Matthew

29
manifest.json Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
{
"package_version": 6,
"format": "usfm",
"generator": {
"name": "ts-desktop",
"build": "132"
},
"target_language": {
"id": "yo",
"name": "Yorùbá",
"direction": "ltr"
},
"project": {
"id": "mat",
"name": "Matthew"
},
"type": {
"id": "text",
"name": "Text"
},
"resource": {
"id": "ulb",
"name": "Unlocked Literal Bible"
},
"source_translations": [],
"parent_draft": {},
"translators": [],
"finished_chunks": []
}