diff --git a/09/03.txt b/09/03.txt index a059a9e5..091edb0b 100644 --- a/09/03.txt +++ b/09/03.txt @@ -1 +1 @@ -\v 3 Si wo o, awon kan ninu awon akowe so laarin ara won, "Okunrin yi je oloro odi (onisokuso)." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nso oro ibi ninu okan yin? \v 5 Ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo wipe a fun Omo Eniyan ni ase lori aye lati se idariji ese,... "o so fun aro na, "dide, gbe enii re, ki o si ma lo ile re." \ No newline at end of file +\v 3 Si wo o, awon kan ninu awon akowe so laarin ara won pe, "Okunrin yi nso oro odi." \v 4 Jesu mo awon ero okan won o si wipe, "Kilode ti e fi nso oro ibi ninu okan yin? \v 5 Ewo ni o rorun lati so, 'A dari ese re ji o' tabi ki a wi, 'dide ki o si rin'? \v 6 Sugbon ki eyin ki o le mo wipe a fun Omo Eniyan ni ase lori aye lati se idariji ese,... "o so fun aro na, "dide, gbe enii re, ki o si ma lo ile re." \ No newline at end of file