Fri Nov 08 2019 19:06:50 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
EDUNOLAOLUWA 2019-11-08 19:06:50 +01:00
parent 18e4717a5d
commit 051b3a8110
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 31 Lọ́gán ni Jésù na ọwọ́ rẹ̀ jáde, ó sì di Pétérù mù ú, ó sì sọ fún pé, "Ìwọ onígbàgbọ́ kékeré, ìwọ́ ṣe ṣ'iyèméjì. \v 32 Nígbànáà ni Jésù àti Pétérù sì wọ nú ọkọ̀, afẹ́fẹ́ náà dáwọ́ dúró. \v 33 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn nínú ọkọ̀ náà sì fi orí balẹ̀ fún Jésù, wọ́n sì wípé, "Ntootọ iwọ ni ọmọ Ọlọ́run."
\v 31 Lọ́gán ni Jésù na ọwọ́ rẹ̀ jáde, ó sì di Pétérù mù ú, ó sì sọ fún pé, "Ìwọ onígbàgbọ́ kékeré, ìwọ́ ṣe ṣ'iyèméjì. \v 32 Nígbànáà ni Jésù àti Pétérù sì wọ nú ọkọ̀, afẹ́fẹ́ náà dáwọ́ dúró. \v 33 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn nínú ọkọ̀ náà sì fi orí balẹ̀ fún Jésù, wọ́n sì wípé, "Nítòótọ́ ìwọ ni ọmọ Ọlọ́run."

View File

@ -1 +1 @@
\v 34 Nigbati wọn si ti rekọja, wọn de orí ilẹ̀ Gẹnẹsarẹti. \v 35 Nígbàtí àwọn ará ìlu náà si mọ Jesu, wọn rán ṣẹ si gbogbo agbegbe yika wọn, wọn si gbe gbogbo aláìlera tọ̀ ọ́ wá. \v 36 Wọ́n bẹ̀ ẹ pe kí wọn o ṣá lè fi ọwọ́ kan ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀: ìwọ̀n gbogbo àwọn tí ó sì fi ọwọ́ wọn kan, ni a mu lára dá .
\v 34 Nígbàtí wọ́n sì ti rékọjá, wọ́n dé orí ilẹ̀ Gẹ́nẹ́sárẹ́tì. \v 35 Nígbàtí àwọn ará ìlu náà sì mọ Jés, wọn rán ṣẹ si gbogbo agbegbe yika wọn, wọn si gbe gbogbo aláìlera tọ̀ ọ́ wá. \v 36 Wọ́n bẹ̀ ẹ pe kí wọn o ṣá lè fi ọwọ́ kan ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀: ìwọ̀n gbogbo àwọn tí ó sì fi ọwọ́ wọn kan, ni a mu lára dá .

View File

@ -44,6 +44,7 @@
"14-10",
"14-13",
"14-22",
"14-28"
"14-28",
"14-31"
]
}