adesinaabegunde_yo_mat_text.../25/17.txt

1 line
270 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 17 Bákanáà èyí tí ó gba tálẹ́ǹtì méjì náà fi tirẹ̀ ṣòwò ó sì jèrè tálẹ́ǹtì méjì mìíràn. \v 18 Ṣùgbọ́n ọmọ ọdọ̀ tí ò gba tálẹ́ǹtì kan, ó wa ihò ní ilẹ̀, ó sì bo owó ọlúwa rẹ̀ mọ́ ibẹ̀.