adesinaabegunde_yo_mat_text.../10/40.txt

1 line
280 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 40 Ẹni tí ó bá gbà yín, èmi ni ó gbà, ẹni tí ó bá sì gbà mí, ó gba ẹni tí ó fi iṣẹ́ rán mi. \v 41 Ẹni tí ó bá gba wolii ní orúkọ wolii yíò gba èrè wolii, ẹni tí ó bá gba olódodo nítorí ó jẹ́ olódodo yóo gba èrè olódodo.