adesinaabegunde_yo_mat_text.../14/06.txt

1 line
244 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 6 Sùgbọ́n nígbàtí ọjọ́ ìbí Hẹ́rọ́dù de, ọmọ'binrin Hẹrọdia sì jo láàrin èrò ti o sì mu inú Hẹ́rọ́dù dùn. \v 7 Nítorínáà ó fi ìbúra ṣe ilérí fun lati fun ní ohunkóhun tí ó ba beerè.