adesinaabegunde_yo_mat_text.../22/25.txt

1 line
491 B
Plaintext
Raw Permalink Normal View History

\v 25 Ọkùnrin méje kan wà. ẹnì kínní fẹ́ ìyàwó ó sì kú. Láì ní ọmọ, ó fi ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ fún arákùnrin rẹ̀. \v 26 Nígbànáà ni arákùnrin kejì se bákannáà, bẹ́ẹ̀sì ni arákùnrin kẹ̀ta, títí lo dé arákùnrin keèje. \v 27 Lẹ́yìn gbogbo wọn , obìnrin náà kú. \v 28 Nísinsìnyí ní àjíǹde, ìyàwó ti tani yóò je nínú àwọn ọkùnrin méjèèje? Nítorí gbogbo wọn ló ti fẹ́ẹ n´ ìyàwó."