Tue Jun 25 2019 08:54:56 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-25 08:54:57 +01:00
parent 2bad8c2577
commit 92425f1d8f
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Ṣùgbọ́n Máíkẹ́lì olú àwọn áńgẹ́lì, nígbà tí ó ń bá èsù se àríyànjíàn lórí àgú ara Mósè, kọ̀ láti sọ̀rò òdì si. Kàkà bẹ́ ó wípé, "Olúwa bá ọ wí!" \v 10 Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn yí sọ̀rò òdì sí ohun gbogbo tí kó yé wọn. Èyí tí ó si yé wọn ní ó ń pawọ́n run, ní èyí tí àwọn ẹranko náà mọ̀. \v 11 Ègbé ni fún wọn! Nítorí wọ́n rìn ní ọ̀na Káínì, wọ́n sì ti wọ inú àsìse Bálámù fún èrè. Wọ́n ti parun sínú ọ̀tẹ̀ Kórà.
\v 9 Ṣùgbọ́n Máíkẹ́lì olú àwọn áńgẹ́lì, nígbà tí ó ń bá èsù ṣe àríyànjíàn lórí àgọ́ ara Mósè, ó kọ̀ láti sọ̀rò òdì si. Kàkà bẹ́ ó wípé, "Olúwa bá ọ wí!" \v 10 Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn yí sọ̀rò òdì sí ohun gbogbo tí kó yé wọn. Èyí tí ó si yé wọn ní ó ń pawọ́n run, ní èyí tí àwọn ẹranko náà mọ̀. \v 11 Ègbé ni fún wọn! Nítorí wọ́n rìn ní ọ̀na Káínì, wọ́n sì ti wọ inú àsìse Bálámù fún èrè. Wọ́n ti parun sínú ọ̀tẹ̀ Kórà.

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Àwọn wọ̀nyí jẹ́ àwọn oníṣé ibi tó farapamọ́ nínú àsè yín. Wọ́n ṣe àsè láì ní ojútì, wọ́n jẹun fún arawọn. Wọ́n jẹ́ kùrukùru tí ò lómi, èyí tí atẹ́gùn ń gbé kiri. Wọ́n jẹ́ igi aláìléso - tí ati hú kúrò tí ó sìti kú. \v 13 Wọ́n dàbí ìjì ńlá lójú òkun, wọ́n ru ìtìjú ara wọn jáde. Wọ́n dàbi ìràwọ̀ tín ráre, àwọn ẹni tí òkùnkùn biribiri ńdúró dè títíláí.
\v 12 Àwọn wọ̀nyí jẹ́ àwọn oníṣé ibi tó farapamọ́ nínú àsè yín. Wọ́n ṣe àsè láì ní ojútì, wọ́n jẹun fún arawọn. Wọ́n jẹ́ kùrukùru tí ò lómi, èyí tí atẹ́gùn ń gbé kiri. Wọ́n jẹ́ igi aláìléso - tí ati hú kúrò tí ó sìti kú. \v 13 Wọ́n dàbí ìjì ńlá lójú òkun, wọ́n ru ìtìjú ara wọn jáde. Wọ́n dàbi ìràwọ̀ tí ń ráre, àwọn ẹni tí òkùnkùn biribiri ńdúró dè títíláí.