diff --git a/01/14.txt b/01/14.txt index c1dd8e3..98a8571 100644 --- a/01/14.txt +++ b/01/14.txt @@ -1 +1 @@ -\v 14 Énọ́kù, ẹni ìkeeje làti Ádámù, sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn, wípé, "Wòó! Olúwa ńbọ̀ pẹ̀lú egbẹgbèrún àwọn ẹni mímó Rẹ̀. \v 15 Ó ń bọ̀ láti ṣe ìdájọ́ gbogbo éníyán. Ó ń bọ̀ láti fi ẹ̀rí ọkàn jẹ́ gbogbo áwọn oní àìwà bíi Ọlórun fún gbogbo iṣé ti wọn ṣe ni ọna aisododo, ati gbogbo oro odi ti awon alaisododo so si I." \v 16 Àwọn wọ̀n yí ni àwọn tí wọ́n ń kùn tí wọ́n sì ń ṣe àwáwí, tí wọ́n ń tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ ara wọn. Wọ́n jẹ́ onígbéraga tí ń fún àwọn ẹlòmíràn ní íyin èké nítorí èrè arawọn. \ No newline at end of file +\v 14 Énọ́kù, ẹni ìkeeje làti Ádámù, sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn, wípé, "Wòó! Olúwa ńbọ̀ pẹ̀lú egbẹgbèrún àwọn ẹni mímó Rẹ̀. \v 15 Ó ń bọ̀ láti ṣe ìdájọ́ gbogbo éníyán. Ó ń bọ̀ láti fi ẹ̀rí ọkàn jẹ́ gbogbo áwọn oní àìwà bíi Ọlórun fún gbogbo iṣé tí wọ́n ṣe ní ọ̀na , ati gbogbo oro odi ti awon alaisododo so si I." \v 16 Àwọn wọ̀n yí ni àwọn tí wọ́n ń kùn tí wọ́n sì ń ṣe àwáwí, tí wọ́n ń tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ ara wọn. Wọ́n jẹ́ onígbéraga tí ń fún àwọn ẹlòmíràn ní íyin èké nítorí èrè arawọn. \ No newline at end of file