Wed Jun 12 2019 12:26:16 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-12 12:26:16 +01:00
parent 20363804be
commit 1dd144864a
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Ènọ́kù, ẹni ìkeeje làti Ádámù, sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn, wípé, "Wòó! Olúwa ńbọ̀ pẹ̀lú egbẹgbèrún àwọn ẹni mímó Rẹ̀. \v 15 Ó ń bọ̀ láti ṣe ìdájọ́ gbogbo éníyán. Ó ń bọ̀ láti fi ẹ̀rí ọkàn jẹ́ gbogbo áwọn alaisododo fun gbogbo ise ti wọn ṣe ni ọna aisododo, ati gbogbo oro odi ti awon alaisododo so si I." \v 16 Àwọn wọ̀n yí ni àwọn tí wọ́n ń kùn tí wọ́n sì ń ṣe àwáwí, tí wọ́n ń tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ ara wọn. Wọ́n jẹ́ onígbéraga tí ń fún à \v 14 Ènọ́kù, ẹni ìkeeje làti Ádámù, sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn, wípé, "Wòó! Olúwa ńbọ̀ pẹ̀lú egbẹgbèrún àwọn ẹni mímó Rẹ̀. \v 15 Ó ń bọ̀ láti ṣe ìdájọ́ gbogbo éníyán. Ó ń bọ̀ láti fi ẹ̀rí ọkàn jẹ́ gbogbo áwọn alaisododo fun gbogbo ise ti wọn ṣe ni ọna aisododo, ati gbogbo oro odi ti awon alaisododo so si I." \v 16 Àwọn wọ̀n yí ni àwọn tí wọ́n ń kùn tí wọ́n sì ń ṣe àwáwí, tí wọ́n ń tẹ̀lé ìfẹ́kùfẹ́ ara wọn. Wọ́n jẹ́ onígbéraga tí ń fún àwọn ẹlòmíràn ní íyin èké nítorí èrè arawọn.

1
01/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 Ṣùgbọ́n \v 18 \v 19