Tue Jun 11 2019 12:22:45 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-11 12:22:45 +01:00
parent 814eefc362
commit 0528adffe9
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Àwọn wọ̀nyí jẹ́ àwọn oníṣé ibi tó farapamọ́ nínú àsè yín. Wọ́n ṣe àsè láì ní ojútì, wọ́n jẹun fún arawọn. Wọ́n jẹ́ kùrukùru tí ò lómi, èyí tí atẹ́gùn ń gbé kiri. Wọ́n jẹ́ igi aláìléso - tí ati hú kúrò tí ó sìti kú. \v 13 Wọ́n dàbí ìjì ńlá lójú òkun, wọ́n ru ìtìjú ara wọn jáde. Wọ́n dàbi ìràwọ̀ tín ráre,
\v 12 Àwọn wọ̀nyí jẹ́ àwọn oníṣé ibi tó farapamọ́ nínú àsè yín. Wọ́n ṣe àsè láì ní ojútì, wọ́n jẹun fún arawọn. Wọ́n jẹ́ kùrukùru tí ò lómi, èyí tí atẹ́gùn ń gbé kiri. Wọ́n jẹ́ igi aláìléso - tí ati hú kúrò tí ó sìti kú. \v 13 Wọ́n dàbí ìjì ńlá lójú òkun, wọ́n ru ìtìjú ara wọn jáde. Wọ́n dàbi ìràwọ̀ tín ráre, àwọn ẹni tí òkùnkùn biribiri ńdúró dè títí