Thu Jun 27 2019 13:39:24 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 13:39:24 +01:00
parent 2025766b25
commit 5290a842a6
3 changed files with 3 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Jẹ́ kí arákùnrin tí kò lówó ṣògo nínú ipò gíga rẹ̀, \v 10 sùgbọ́n ọlọ́rọ̀ nínú ipò ìrẹ̀sílẹ̀ rẹ̀, nítorí yóò kọjá lọ gẹ́gẹ́bí ìtànná koríko ìgbẹ́. \v 11 Nítorí oòrùn ń ráǹ pẹ̀lú oru iná tí ó ń jó, ó sì gbẹ àwọn koríko. Òdòdó já lulẹ̀, ẹwà rẹ̀ sí sègbé. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ọlọ́rọ̀ yóò parẹ́ ní àáríń gbùgbùn ìrìn àjò rẹ̀.
\v 9 Jẹ́ kí arákùnrin tí kò lówó ṣògo nínú ipò gíga rẹ̀, \v 10 sùgbọ́n ọlọ́rọ̀ nínú ipò ìrẹ̀sílẹ̀ rẹ̀, nítorí yóò kọjá lọ gẹ́gẹ́bí ìtànná koríko ìgbẹ́. \v 11 Nítorí oòrùn ń ráǹ pẹ̀lú oru iná tí ó ń jó, ó sì gbẹ àwọn koríko. Òdòdó já lulẹ̀, ẹwà rẹ̀ sí sègbé. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ọlọ́rọ̀ yóò parẹ́ ní àárín gbùgbùn ìrìn àjò rẹ̀.

View File

@ -1 +1 @@
\v 12 Ìbùkún ni fún ọkùnrin na tí ó fi ara da ìdánwò. Nítorí lẹ́yìn tí ó bá yege ìdánwò, yóò gba adé ìyè, tí a ti sèlérí fún àwọn tí ó fẹ́ràn Ọlọ́run. \v 13 Kí ẹnikẹ́ni má se ṣọ wípé Ọlọ́run ni óhún dán òhun wò nígbà tí ó bá ń la ìdáwò kọjá, nítorí Ọlọ́run kìí fi ibi dániwò, Kìí si dán ẹnikẹ́ni wò.
\v 12 Ìbùkún ni fún ọkùnrin na tí ó fi ara da ìdánwò. Nítorí lẹ́yìn tí ó bá yege ìdánwò, yóò gba adé ìyè, tí a ti sèlérí fún àwọn tí ó fẹ́ràn Ọlọ́run. \v 13 Kí ẹnikẹ́ni má se ṣọ wípé Ọlọ́run ni óhún dán òhun wò nígbà tí ó bá ń la ìdáwò kọjá, nítorí Ọlọ́run kìí fi ibi dán ènìyàn wò, Kìí si dán ẹnikẹ́ni wò.

View File

@ -41,6 +41,7 @@
"01-01",
"01-04",
"01-06",
"01-09",
"01-12",
"01-14",
"01-17",