Thu Jun 27 2019 15:19:24 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 15:19:24 +01:00
parent f9bb8c7fea
commit 44d8621657
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 Tí ẹnikẹ́ni bá ro ara rẹ̀ bí olùfọkansìn, ṣùgbọ́n tí kò kó ahọ́n rẹ̀ ní ìjánu, ó ń tan ọkàn rẹ̀, ìfọkànsìn rẹ̀ sì jẹ́ aláìnílárí. \v 27 Ìsìn tí ó mọ́, tí kò sì ní àbàwọ́n níwájú Ọlọ́run wa àti Bàbá ni èyí: láti ran aláìníbaba àti àwọn opó lọ́wọ́ nínú ìpọ́njú wọn, àti láti pa ara ẹni mọ́ láìní àbàwón nínú ayé yìí.
\v 26 Tí ẹnikẹ́ni bá ro ara rẹ̀ bí olùfọkansìn, ṣùgbọ́n tí kò kó ahọ́n rẹ̀ ní ìjánu, ó ń tan ọkàn rẹ̀, ìfọkànsìn rẹ̀ sì jẹ́ aláìnílárí. \v 27 Ìsìn tí ó mọ́, tí kò sì ní àbàwọ́n níwájú Ọlọ́run wa àti Bàbá ni èyí: láti ran aláìníbaba àti àwọn opó lọ́wọ́ nínú ìpọ́njú wọn, àti láti pa ara ẹni mọ́ láìní àbàwọ́n nínú ayé yìí.

View File

@ -1 +1 @@
\c 2 \v 2 \v 1 Ẹ̀yin ará mi, ẹ má se di ìgbàgbọ́ nínú Krístì Olúwa ògo mú, pẹ̀lú ojúsàájú sí àwọn kan. ẹnìkan bá wọ inú ìpàgọ́ yín tí ó wọ òrùka wúrà àti àwọn asọ tí ó dára, tí ọkùnrin míràn tálákà tí ó jẹ́ wọlé nínú asọ eléèrí. \v 3 Tí o bá sì wo alásọ dáradára nì, tí o sì wípé, jókòó ní ibi dáradára yìí, tí o sì sọ fún tálákà wipe dúró sí ọ̀hún, tàbí jókòó ní ibi ẹsẹ̀ mi, \v 4 ẹ̀yin kò a ti ṣe ìdájọ́ láàárín ara yín bí? Ẹ̀yin kò a ti di onídàájọ́ pẹ̀lú èrò ibi bí?
\c 2 \v 1 Ẹ̀yin ará mi, ẹ má se di ìgbàgbọ́ nínú Krístì Olúwa ògo mú, pẹ̀lú ojúsàájú sí àwọn kan. ẹnìkan bá wọ inú ìpàgọ́ yín tí ó wọ òrùka wúrà àti àwọn asọ tí ó dára, tí ọkùnrin míràn tálákà tí ó jẹ́ wọlé nínú asọ eléèrí. \v 3 Tí o bá sì wo alásọ dáradára nì, tí o sì wípé, jókòó ní ibi dáradára yìí, tí o sì sọ fún tálákà wipe dúró sí ọ̀hún, tàbí jókòó ní ibi ẹsẹ̀ mi, \v 4 ẹ̀yin kò a ti ṣe ìdájọ́ láàárín ara yín bí? Ẹ̀yin kò a ti di onídàájọ́ pẹ̀lú èrò ibi bí?

View File

@ -46,8 +46,8 @@
"01-14",
"01-17",
"01-22",
"01-26",
"02-title",
"02-01",
"02-05",
"02-08",
"02-10",