adesinaabegunde_yo_jas_text.../01/17.txt

1 line
364 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti ẹ̀bùn tí ó péye wá làti òkè. A máa sọ̀kalẹ̀ wá láti ọ̀dọ̀ Baba ìmọ́lẹ̀. Pẹ̀lú rẹ̀, kò sí àyídá- yidà tàbí ìyí ọkàn padà. \v 18 Ọlọ́run yàn láti fún wa ní ìbí nípa ọ̀rọ̀ òtítọ́, kí á le jẹ́ irúfẹ́ èso àkọ́so láàrín ohun gbogbo tí Ó dá.