adesinaabegunde_yo_gal_text.../01/06.txt

1 line
426 B
Plaintext

\v 6 Ìyàlẹ́nu lójẹ́ fún mi pé ẹ̀yin ń tètè yí padà kúrò lọ́dọ̀ ẹni tí ó pè yín nípasẹ̀ ore ọ̀fẹ́ Krístì. Ìyàlénu lójẹ́ fún mi pé ẹ̀yín ń yí sí ìhìnrere mìíràn. \v 7 Èyí kìí ṣe láti sọ wípé ìhìnrere mìíràn wà, ṣùgbón àwọn ènìyàn kan wà tí ó ń yọ yín lẹ́nu tí wọ́n sìí fẹ́ láti yí ìhìnrere ti Krístì padà.