Thu Jun 27 2019 09:21:29 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 09:21:29 +01:00
parent 80a9b946e5
commit e8c1eccc4b
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 1 \v 1 Pọ́ọ̀lù, àpọ́stélì - tí kìí ṣe àpọ́stélì ti ènìyàn tàbí nípasẹ̀ ìránṣẹ́ ènìyàn ṣùgbọ́n nípasẹ̀ Jésù Krístì àti Ọlọ́run Baba, ẹni tí ó jíi dìde kúrò ní ipò àwọn òkú - \v 2 àti gbogbo àwọn arákùnrin t wà pẹ̀lú mi, sí gbogbo ìjọ Galátíà:
\c 1 \v 1 Pọ́ọ̀lù, àpọ́stélì - tí kìí ṣe àpọ́stélì ti ènìyàn tàbí nípasẹ̀ ìránṣẹ́ ènìyàn ṣùgbọ́n nípasẹ̀ Jésù Krístì àti Ọlọ́run Baba, ẹni tí ó jíi dìde kúrò ní ipò àwọn òkú - \v 2 àti gbogbo àwọn arákùnrin tí ó wà pẹ̀lú mi, sí ìjọ Galátíà:

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Ore ọ̀fẹ́ àti àláfíà fún n yín láti ọ̀dọ Baba Ọlọ́run wa àti Jésù Krístì, \v 4 ẹni tí ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí ẹ̀sẹ̀ wa kí ó le gbàwá lọ́wọ́ ìgbà búburú yìí, ní ìbáámu pẹ̀lú ìfé Ọlọ́run Baba wa, \v 5 tirẹ̀ ni ògo láí àti láí láí. Àmín.
\v 3 Ore ọ̀fẹ́ àti àláfíà fún yín láti ọ̀dọ Baba Ọlọ́run wa àti Jésù Krístì, \v 4 ẹni tí ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí ẹ̀sẹ̀ wa kí ó le gbàwá lọ́wọ́ ìgbà búburú yìí, ní ìbáámu pẹ̀lú ìfé Ọlọ́run Baba wa, \v 5 tirẹ̀ ni ògo láí àti láí láí. Àmín.