Wed Oct 16 2019 13:50:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
Oluwamayowa 2019-10-16 13:50:44 +01:00
commit dd1c74c0e4
12 changed files with 67 additions and 0 deletions

1
01/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 1 Pọ́ọ̀lù, àpọstélì - àpọstélì tí kìí ṣe láti ọ̀dọ̀ ènìyàn tàbí nípasẹ̀ ẹnikẹ́ni, bíkòṣe nípasẹ̀ Jésù Krístì àti Ọlọ́run Baba, tí Ó jí I dìde kúrò nínú àwọn òkú - \v 2 àti gbogbo àwọn ará tí ó wà pẹ̀lú mi, sí àwọn ìjọ Gàlátíà:

1
01/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Oore-ọ̀fẹ́ fún yín àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Bàbáa wa àti Jésù Krístì Olúwa, \v 4 Ẹni tí Ó fi ara Rẹ̀ sílẹ̀ fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa kí Ó ba lè gbà wá lọ́wọ́ ayé ibi ìsinsìn yìí, gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run òun Bàbá wa, \v 5 Ẹni tí ògo yẹ fún láí àti láíláí. Àmín.

1
01/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Ó yà mí lẹ́nu pé ẹ ń tètè yà kúrò lọ́dọ̀ Ẹni tí Ó pè yín nípa oore-ọ̀fẹ́ Krístì. Ó yà mí lẹ́nu pé ẹ ń yà sí ìhìnrere tó yàtọ̀. \v 7 Èyí kò sọ pé ìhìnrere mìíràn wà, ṣùgbọ́n àwọn kan wà tó ń dààmú yín tí wọ́n sì fẹ́ yí ìhìnrere Krístì padà.

1
01/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 8 Ṣùgbọ́n kódà bó ṣe àwa tàbí áńgẹlì kan láti ọ̀run wá ló bá kéde ìhìnrere mìíran fún yín yàtọ̀ sí èyí tí a ti kéde rẹ̀ fún yín tẹ́lẹ̀, kí Olúwa fi ẹni bẹ́ẹ̀ ré. \v 9 Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ tẹ́lẹ̀, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni mo tún sọ, "Bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìhìnrere mìíran fún yín yàtọ̀ sí èyí tí ẹ ti gbà tẹ́lẹ̀, kí Olúwa fi ẹni bẹ́ẹ̀ ré." \v 10 Ṣé mo ha ń wá ìtẹ́wọ́gbà ènìyàn ni, àbí ti Ọlọ́run? Ṣé mo ń dù láti tẹ́ ènìyàn lọ́rùn ni? Tí mo bá ṣì ń dù láti tẹ́ ènìyaǹ lọ́rùn, èmi kìí ṣe ìránṣẹ́ Krístì.

1
01/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀, ará, pé ìhìnrere tí mo kéde rẹ̀ fún yín kìí ṣe ti ènìyàn. \v 12 Èmi kò gbà á láti ọwọ́ ènìyàn kankan, bẹ́ẹ̀ ni a kò sì fi kọ́ mi. Dípo bẹ́ẹ̀, ó jẹ́ nìpa ìfihàn Jésù Krístì sí mi.

BIN
01/13.txt Normal file

Binary file not shown.

1
01/15.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 15 Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọlọ́run, Ẹni tí Ó ti yà mí s'ọ́tọ̀ láti inú ìyá mi wá, tí Ó sì pè mí nípa oore-ọ̀fẹ́ Rẹ̀, \v 16 fẹ́ láti ṣ'àfihàn Ọmọ Rẹ̀ nínú mi, kí èmi kí ó lè kéde Rẹ̀ láàárín àwọn kèfèrí, èmi kò gbèrò pẹ̀lú ẹnikẹ́ni lójúkannáà. \v 17 Èmi kò gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù s'ọ́dọ̀ àwọn tí wọ́n ti di àpọ́stélì ṣáájú mi. Dípò bẹ́ẹ̀, mo lọ sí Arábíà lẹ́yìn nàá mo padà sí Damáskù.

1
01/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta mo gòkè lọ sí Jerúsálẹ́m̀ láti mọ Kééfà, mo sì wà pẹ̀lú rẹ̀ fún ọjọ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. \v 19 Èmi kò rí ọ̀kankan nínú àwọn àpọ́stélì tó kù àyàfi Jákọ́bù, arákùnrin Olúwa. \v 20 Mo fi ń dá yín lójú níwájú Ọlọ́run pé èmi kò parọ́ nínú àwọn ohun tì mo ń kọ sí yín wọ̀nyí.

1
01/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Lẹ́yìn náà ni mo lọ sí Síríà àti Silísíà. \v 22 Èmi kò tíì di mímọ̀ lójúkojú pẹ̀lú àwọn ìjọ Jùdíà tó wà nínú Krístì. \v 23 Wọ́n kàn gbọ́ tí àwọn kan ń sọ pé, "Ọkùnrin náà tí ó ń ṣe inúnibíni sí wa nígbà kan rí ti wá ń kéde ìgbàgbọ́ náà tí ó gbìyànjú láti parun." \v 24 Nítorí náà wọ́n yin Ọlọ́run lógo nítorí mi.

29
LICENSE.md Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
# License
## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0)
This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/.
### You are free to:
* **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format
* **Adapt** — remix, transform, and build upon the material
for any purpose, even commercially.
The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms.
### Under the following conditions:
* **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work.
* **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original.
**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits.
### Notices:
You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation.
No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material.
This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/).

1
front/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Galatians

29
manifest.json Normal file
View File

@ -0,0 +1,29 @@
{
"package_version": 6,
"format": "usfm",
"generator": {
"name": "ts-desktop",
"build": "132"
},
"target_language": {
"id": "yo",
"name": "Yorùbá",
"direction": "ltr"
},
"project": {
"id": "gal",
"name": "Galatians"
},
"type": {
"id": "text",
"name": "Text"
},
"resource": {
"id": "ulb",
"name": "Unlocked Literal Bible"
},
"source_translations": [],
"parent_draft": {},
"translators": [],
"finished_chunks": []
}