Tue May 11 2021 13:25:15 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
iconcept 2021-05-11 13:25:16 +01:00
parent 7fbf56cbc6
commit d0c6a8f969
3 changed files with 3 additions and 15 deletions

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 25 Bí a bá ńgbé nínú Un Ẹ̀mí, ẹ jẹ́ kí a rìn nípa ti Ẹ̀mí. \v 26 A sì gbọdọ̀ yẹra fún ìdíwọ́ tí a ó fi mú ara wa bínú tí a ó sì máa jẹ owú ara wa.
=======
\v 25 Tí a bá ń gbé nípa ti ẹ̀mí, ẹ jẹ́ ká máa rìn nípa ti ẹ̀mí náà. \v 26 Ẹ má ṣe jẹ́ ká gbéraga, nípa mímú ara wa bínú, ṣíṣe ìlara ara wa.
>>>>>>> 10538a46292f4c0fa07bc141c06f7dbc01bf3b28
\v 25 Tí a bá ń gbé nípa ti ẹ̀mí, ẹ jẹ́ ká máa rìn nípa ti ẹ̀mí náà. \v 26 Ẹ má ṣe jẹ́ ká gbéraga, nípa mímú ara wa bínú, ṣíṣe ìlara ara wa.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\c 6 \v 1 Ẹ̀yin ará, bí ẹ bá mú ẹnì kan nínú ẹ̀ṣẹ̀, kí ẹ̀yin tí o wà nínú ẹ̀mí mú irú ẹni bẹ́ẹ̀ padàbọ̀sípò ní ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀. Ẹ kíyèsára yín , kí ẹ̀yin náà má bàá bọ́ sínú ìdáǹwò. \v 2 Ẹ máa ru ẹrù ọmọ nìkejìi yín, kí ẹ le mú òfin Krístì ṣẹ.
=======
\c 6 \v 1 Ará tí ẹ bá mú enìkan nínú àwọn ìrékọjá kan, kí ẹ̀yin tí ń ṣe ẹni ti ẹ̀mí kó ṣe ìmúpadàbọ̀sípò rẹ̀ nínú ẹ̀mí ìwàpẹ̀lẹ́. Ẹ máa ṣe àníyàn ara yín, kí ẹ má baà fa ara yín sínú ìdánwò. \v 2 Ẹ ma ru ẹrù ara yín, nípasẹ̀ èyí kí òfin Krístì di mímúṣẹ.
>>>>>>> 10538a46292f4c0fa07bc141c06f7dbc01bf3b28
\c 6 \v 1 Ará tí ẹ bá mú enìkan nínú àwọn ìrékọjá kan, kí ẹ̀yin tí ń ṣe ẹni ti ẹ̀mí kó ṣe ìmúpadàbọ̀sípò rẹ̀ nínú ẹ̀mí ìwàpẹ̀lẹ́. Ẹ máa ṣe àníyàn ara yín, kí ẹ má baà fa ara yín sínú ìdánwò. \v 2 Ẹ ma ru ẹrù ara yín, nípasẹ̀ èyí kí òfin Krístì di mímúṣẹ.

View File

@ -1,5 +1 @@
<<<<<<< HEAD
\v 3 Bí ẹnikẹ́ni bá rò pé òun jẹ́ ǹkan, nígbàtí kò já mọ́ ǹkankan, ó tan ara rẹ̀ jẹ. \v 4 Kí olúkúlùkù máa yẹ iṣẹ́ rẹ̀ wò, nípa bẹ́ẹ̀ ìdí láti gbéraga yoò wà nínú ara rẹ̀ nìkan ṣùgbọ́n kò sí ní sí nínu elòmírań. \v 5 Nítorí olúkúlùkù ni yóò ru ẹrù ara rẹ̀.
=======
\v 3 Nítorí tí ẹnikẹ́ni bá rò pé òún ṣe pàtàkì nígbàtí kò já mọ́ nkankan, ó tan ara rẹ̀ jẹ. \v 4 Kí oníkálukú yẹ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ wò, èrèdí fún láti fọ́n-nu yóò sì wà nínú ara rẹ̀ nìkan láìsí nínú ẹlòmíràn. \v 5 Nítorí oníkálukú ni yíò gbé ẹrù ara rẹ̀.