Thu Jun 27 2019 09:31:29 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
ebb1616141
commit
7c6ea9e4f6
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángéli kan láti ọ̀run ló bá kéde ìhìnrere míràn fún yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún yín, jẹ́ kí ó dí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí ódi ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi ń wá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Njẹ èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn lórùn bi? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì.
|
||||
\v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángéli kan láti ọ̀run ló bá kéde ìhìnrere míràn fún yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún yín, jẹ́ kí ó dí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí ódi ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi ń wá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Njẹ èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn Ọlọ́run bí? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì.
|
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 11 Nítorí mo fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó mọ̀, ará, pẹ́ ìyìnrere tí mo ń kéde kìí ṣe ti ìhìnrere ti ènìyàn. \v 12 Èmi kò gbàá lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, bẹ́ẹ̀ni akò kọ́ mi. Ṣùgbọ́n, nípa ìfihàn jésù krístì sími ni.
|
||||
\v 11 Nítorí mo fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó mọ̀, ará, pẹ́ ìhìnrere tí mo ń kéde kìí ṣe ti ìhìnrere ti ènìyàn. \v 12 Èmi kò gbàá lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, bẹ́ẹ̀ni akò kọ́ mi. Ṣùgbọ́n, nípa ìfihàn jésù krístì sími ni.
|
Loading…
Reference in New Issue