Wed Jun 26 2019 12:35:57 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
f6e47d62d5
commit
6cf8752ba0
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 13 Ẹ̀yín ti gbọ́ nípa ìgbé ayé mi tẹ́lẹ̀ rí nínú ẹ̀sìn Júù, bí moti ṣe gbógun ti ìjọ ti Ọlọ́run ju bí ó ṣe yẹ lọ àti bí mo ti ṣe ń gbìyànjú láti paárun. \v 14 Mo tayọ nínú ẹ̀sìn Júù ju púpò nínú àwon tí ó jẹ́ akẹgbẹ́èmi, láti ara wọn ènìyàn mi. Bí mo ti ṣe ní ìtara gidigidi fún èsìn àwọn bábà mi nìyí.
|
||||
\v 13 Ẹ̀yín ti gbọ́ nípa ìgbé ayé mi tẹ́lẹ̀ rí nínú ẹ̀sìn Júù, bí moti ṣe gbógun ti ìjọ ti Ọlọ́run ju bí ó ṣe yẹ lọ àti bí mo ti ṣe ń gbìyànjú láti paárun. \v 14 Mo tayọ nínú ẹ̀sìn Júù ju púpò nínú àwon tí ó jẹ́ akẹgbẹ́èmi, láti ara àwọn ènìyàn mi. Bí mo ti ṣe ní ìtara gidigidi fún èsìn àwọn bábà mi nìyí.
|
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 15 Ṣugbọ́n níbgàtí Ọlọ̀rún tí ó ti yamí sọ́tọ̀, láti inú ìyá mi wa tí ó sì pèmí nípasè ore ọ̀fẹ́ rè, \v 16 tí ṣe inú dídùn láti fi ọmọ rẹ hàn nínú mi, kí n le kéde rè láàrín àwọn kèfèrí, emí kò bá ẹran ara atí ẹ̀jẹ̀ gbèrò papọ̀ lésẹ̀kẹsẹ̀ \v 17 Èmi kò lọ sí Jerusalemu lọ́dọ̀ àwọn kèfèrí lọ́dọ̀ àwọn tí ó ti di àwọn àpọ́stélì síwájú mi, dípò mo lọ sí Arébíà mo sì padà sí damáskúsì.
|
||||
\v 15 Ṣugbọ́n nígbàtí Ọlọ̀rún tí ó ti yamí sọ́tọ̀, láti inú ìyá mi wa tí ó sì pèmí nípasè ore ọ̀fẹ́ rè, \v 16 tí ṣe inú dídùn láti fi ọmọ rẹ hàn nínú mi, kí n le kéde rè láàrín àwọn kèfèrí, emí kò bá ẹran ara atí ẹ̀jẹ̀ gbèrò papọ̀ lésẹ̀kẹsẹ̀ \v 17 Èmi kò lọ sí Jerusalemu lọ́dọ̀ àwọn kèfèrí lọ́dọ̀ àwọn tí ó ti di àwọn àpọ́stélì síwájú mi, dípò mo lọ sí Arébíà mo sì padà sí damáskúsì.
|
Loading…
Reference in New Issue