Wed Jun 26 2019 12:37:57 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 12:37:57 +01:00
parent 6cf8752ba0
commit 3b1e03eb2c
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Ṣugbọ́n nígbàtí Ọlọ̀rún tí ó ti yamí sọ́tọ̀, láti inú ìyá mi wa tí ó sì pèmí nípasè ore ọ̀fẹ́ rè, \v 16 tí ṣe inú dídùn láti fi ọmọ rẹ hàn nínú mi, kí n le kéde rè láàrín àwọn kèfèrí, emí kò bá ẹran ara atí ẹ̀jẹ̀ gbèrò papọ̀ lésẹ̀kẹsẹ̀ \v 17 Èmi kò lọ sí Jerusalemu lọ́dọ̀ àwọn kèfèrí lọ́dọ̀ àwọn tí ó ti di àwọn àpọ́stélì síwájú mi, dípò mo lọ sí Arébíà mo sì padà sí damáskúsì.
\v 15 Ṣugbọ́n nígbàtí Ọlọ̀rún, tí ó ti yamí sọ́tọ̀ láti inú ìyá mi wa, tí ó sì pèmí nípasè ore ọ̀fẹ́ Rè, \v 16 tí ṣe inú dídùn láti fi Ọmọ Rẹ hàn nínú mi, kí n le kéde rè láàrín àwọn kèfèrí, emí kò bá ẹran ara atí ẹ̀jẹ̀ gbèrò papọ̀ lésẹ̀kẹsẹ̀ \v 17 Èmi kò lọ sí Jerusalemu lọ́dọ̀ àwọn kèfèrí lọ́dọ̀ àwọn tí ó ti di àwọn àpọ́stélì síwájú mi, dípò mo lọ sí Arébíà mo sì padà sí damáskúsì.