adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/31.txt

1 line
391 B
Plaintext

\v 31 "Nitori idi eyi ọkunrin yoo fi Baba ati iya rẹ silẹ, yoo si darapọ mọ iyawo rẹ, awọn mejeji yoo si di ara kan." \v 32 Otitọ ti o pamọ yi (jẹ eyi ti o) ga - sugbọn emi n sọ nipa Kristi ati ijọ. \v 33 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹnikọọkan yin pẹlu gbọdọ fẹran iyawo re, begẹbi ara oun tikararẹ, ati wipe iyawo naa gbọdọ bọwọ fun ọkọ re.