\v 15 Ẹ se akiyesi bi ẹ se n gbe igbe aye yin - kii se gẹgẹbi awọn alaigbọn sugbọn bi ọlọgbọn, \v 16 Ẹ ra igba pada nitori buburu ni awọn ọjọ. \v 17 Nitorinaa, ẹ mase se omugọ, sugbọn ẹ ni oye ohun ti ifẹ Ọlọrun jẹ.