adesinaabegunde_yo_eph_text.../02/01.txt

1 line
441 B
Plaintext

\c 2 \v 1 Sugon nipa ti yin, eyin ti ku ninu ese ati irekoja yin. \v 2 Ninu ese ati irekoja wonyi ni e n gbe gegebi ise ti aye yi. Eyin ngbe aye gegebi fun alakoso ati awon alase ofurufu, emi naa ti nsise ninu awon omo l=alaigboran. \v 3 Nigba kan ri, gbogbo wa n gbe laarin awon eniyan wonyi, nipa mimu ife buruku ti eda ese wa sisise, ati lati maa mu ife ti ara ati ti okan wa si imuse. Nipa iseda omo ibinu, gegebi gbogbo eda eniyan.