adesinaabegunde_yo_eph_text.../01/19.txt

1 line
689 B
Plaintext

\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ nínú àwon ọ̀run. \v 21 Ó mú kí Krístì jòkó rékọjá gbogbo ìsàkoso àti àsẹ àti agbára, àti ìjọba àti orúkọ kórukọ́ tí a lè dá. Krístì yóò se àkoso, kìí se ní ayé yìí nìkan ṣùgbọ́n, kódà ní ayé tí ḿbọ̀ pẹ̀lú.