adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/17.txt

1 line
295 B
Plaintext

\v 17 Ẹ si mu akoto igbala at ida ẹmi, tii se ọrọ Ọlọrun. \v 18 Pẹlu gbogbo adura at isipẹ, ẹ gbadura ni igba gbogbo ninu Ẹmi. Pẹlu ọkan yii, ẹ ma sọna ni igba gbogbo pẹlu ipamọra gbogbo, gẹgẹbi ẹ se n gbadura fun gbogbo awọn eniyan, Ọlọrun, mimọ