adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/14.txt

1 line
321 B
Plaintext

\v 14 Ẹ duro, nitorinaa, lẹyin igba ti ẹ ba ti fi ọja igbanu ti otitọ at igbaya ti ododo ni mo ara. \v 15 Bẹni bata fun ẹsẹ yin, ẹ gbe imura to setan lati polungo iyinrere ti alafia wọ. \v 16 Ni gbogbo ohunkohn ẹ mu apata igbagbọ, nipa eyi ti ẹyin yoo fi lee pa ina awọn ọfa ẹni ibi ni.